Ecclesiastes 8:16 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Nígbà tí mo fi tọkàntọkàn pinnu láti wá ọgbọ́n ati láti wo iṣẹ́ tí wọn ń ṣe ní ayé, bí eniyan kì í tíí fi ojú ba oorun tọ̀sán-tòru,
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nigbati mo fi aiya mi si ati mọ̀ ọgbọ́n, on ati ri ohun ti a ṣe lori ilẹ: (ẹnikan sa wà pẹlu ti kò fi oju rẹ̀ ba orun li ọsan ati li oru.)
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà tí mo lo ọkàn mi láti mọ ọgbọ́n àti láti wo wàhálà ènìyàn ní ayé.