Ephesians 1:16 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
kò sinmi láti máa dúpẹ́ nítorí yín, mo sì ń ranti yín ninu adura mi.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Emi kò si simi lati mã dupẹ nitori nyin, ati lati mã darukọ nyin ninu adura mi;
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Èmi kò sì sinmi láti máa dúpẹ́ nítorí yín, àti láti máa rántí yín nínú àdúrà mi;