Ephesians 1:20 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ó fi agbára yìí hàn ninu Kristi nígbà tí ó jí i dìde ninu òkú, tí ó mú un jókòó ní ọwọ́ ọ̀tún rẹ̀ lọ́run.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Eyiti o ti ṣiṣẹ ninu Kristi, nigbati o ti jí dide kuro ninu okú, ti o si fi i joko li ọwọ́ ọtún ninu awọn ọrun,
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
èyí tí ó fi sínú Kírísítì, nígbà tí o ti jí dìde kúrò nínú òkú, tí ó sì mú un jòkòó lọ́wọ́ ọ̀tún nínú àwọn ọ̀run.