Ephesians 4:8 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nítorí èyí ni Ìwé Mímọ́ ṣe sọ pé, “Nígbà tí ó lọ sí òkè ọ̀run, ó kó àwọn ìgbèkùn lẹ́yìn, ó sì fi ẹ̀bùn fún àwọn eniyan.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitorina o wipe, Nigbati o gòke lọ si ibi giga, o di igbekun ni igbekun, o si fi ẹ̀bun fun enia.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nitorí náà a wí pé: “Nígbà tí ó gókè lọ sí ibi gíga, ó di ìgbékùn ni ìgbékùn, ó sì fi ẹ̀bùn fun ènìyàn.”