Ephesians 5:12 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nítorí àwọn ohun tí wọn ń ṣe níkọ̀kọ̀ tilẹ̀ ti eniyan lójú láti sọ.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitori itiju tilẹ ni lati mã sọ̀rọ nkan wọnni ti nwọn nṣe nikọ̀kọ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí ìtìjú tilẹ̀ ni láti máa sọ̀rọ̀ nǹkán wọ̀n-ọn-nì tí àwọn aláìgbọ́ràn ń ṣe ní ìkọ̀kọ̀.