Ephesians 5:16 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ẹ lo gbogbo àkókò yín dáradára nítorí àkókò tí a wà yìí burú.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ẹ mã ra ìgba pada, nitori buburu li awọn ọjọ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ẹ máa ra ìgbà padá, nítorí búburú ní àwọn ọjọ́.