Ephesians 5:3 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Kí á má ṣe gbúròó ìwà àgbèrè, tabi oríṣìíríṣìí ìṣekúṣe, tabi ojúkòkòrò láàrin àwọn eniyan Ọlọrun.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ṣugbọn àgbere, ati gbogbo ìwa ẽrí, tabi ojukòkoro, ki a má tilẹ darukọ rẹ̀ larin nyin mọ́, bi o ti yẹ awọn enia mimọ́;
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ṣùgbọ́n àgbèrè àti gbogbo ìwà-èérì, tàbi ojúkòkòrò, kí a má tilẹ̀ dárúkọ rẹ̀ láàárin yín mọ́, bí ó ti yẹ àwọn ènìyàn mimọ;