Ephesians 5:7 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nítorí náà ẹ má ṣe fi ara wé wọn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitorina ẹ máṣe jẹ alajọpin pẹlu wọn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí náà ẹ má ṣe jẹ́ alájọpín pẹ̀lú wọn.