Ephesians 6:1 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ẹ̀yin ọmọ, ẹ máa gbọ́ ti àwọn òbí yín nítorí pé bẹ́ẹ̀ ni ó dára.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
ẸNYIN ọmọ, ẹ mã gbọ ti awọn õbi nyin ninu Oluwa: nitoripe eyi li o tọ́.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ẹ̀yín ọmọ, ẹ máa gbọ tí àwọn òbí i yín nínú Olúwa: nítorí pé èyí ní ó tọ́.