Esther 2:13 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Nígbà tí wundia kan bá ń lọ siwaju ọba, lẹ́yìn tí ó ba ti ṣe gbogbo nǹkan tí ó yẹ, ó lè gba ohunkohun tí ó bá fẹ́ mú lọ láti ilé àwọn ayaba.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Bayi ni wundia na iwá si ọdọ ọba; ohunkohun ti o ba bère li a si ifi fun u lati ba a lọ, lati ile awọn obinrin lọ si ile ọba.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Báyìí ni yóò ṣe lọ ṣíwájú ọba: ohunkóhun tí ó bá béèrè ni wọ́n fi fún-un láti inú ilé àwọn obìnrin lọ sí ààfin ọba.