Esther 3:11 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ọba sọ fún un pé, “Má wulẹ̀ san owó kankan, àwọn eniyan náà wà ní ìkáwọ́ rẹ, lọ ṣe wọ́n bí o bá ti fẹ́.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ọba si wi fun Hamani pe, a fi fadaka na bùn ọ, ati awọn enia na pẹlu, lati fi wọn ṣe bi o ti dara loju rẹ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ọba sọ fún Hámánì pé, “pa owó náà mọ́” “kí o sì ṣe ohun tí ó wù ọ́ fún àwọn ènìyàn náà.”