Esther 4:13 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
ó tún ranṣẹ sí Ẹsita pada, ó ní, “Má rò pé ìwọ nìkan óo là láàrin àwọn Juu, nítorí pé o wà ní ààfin ọba.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nigbana ni Mordekai sọ ki a da Esteri lohùn pe, Máṣe rò ninu ara rẹ pe, iwọ o là ninu ile ọba jù gbogbo awọn Ju lọ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ó sì rán ìdáhùn yí sí i pé; “Má ṣe rò pé nítorí pé ìwọ wà nílé ọba ìwọ nìkan lè yọ láàrin gbogbo àwọn Júù.