Esther 5:3 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ọba bi ayaba Ẹsita pé, “Ẹsita, kí ló dé? Kí ni ẹ̀dùn ọkàn rẹ? A óo fún ọ, títí dé ìdajì ìjọba mi.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nigbana ni ọba bi i pe, kini iwọ nfẹ́, Esteri ayaba? ati kini ẹ̀bẹ rẹ̀? ani de idajì ijọba li a o si fi fun ọ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà náà ni ọba béèrè pé, “kí ni ó dé, ayaba Ẹ́sítà? Kí ni o fẹ́? Bí ó tilẹ̀ ṣe títí dé ìdajìn mi ìjọba àní, a ó fi fún ọ.”