Esther 8:12 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Àṣẹ yìí gbọdọ̀ múlẹ̀ ní gbogbo ilẹ̀ Pasia, ní ọjọ́ tí wọ́n yàn láti pa gbogbo àwọn Juu, ní ọjọ́ kẹtala oṣù kejila, tíí ṣe oṣù Adari.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Li ọjọ kanṣoṣo ni gbogbo ìgberiko Ahaswerusi ọba, li ọjọ kẹtala, oṣù kejila ti iṣe oṣù Adari.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ọjọ́ tí a yàn fún àwọn Júù ní gbogbo agbégbé ọba Ṣéríṣésì láti ṣe nǹkan yìí ni ọjọ́ kẹtàlá èyí tí í ṣe oṣu kejìlá, oṣù Ádárì.