Esther 9:29 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ẹsita Ayaba, ọmọbinrin Abihaili, ati Modekai, tíí ṣe Juu kọ ìwé láti fi ìdí ìwé keji nípa Purimu múlẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nigbana ni Esteri ayaba, ọmọbinrin Abihaili, ati Mordekai, ara Juda, fi ọlá gbogbo kọwe, lati fi idi iwe keji ti Purimu yi mulẹ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Bẹ́ẹ̀ ni Ẹ́sítà ayaba, ọmọbìnrin Ábíháílì, pẹ̀lú Módékáì aráa Júù, kọ̀wé pẹ̀lú àṣẹ láti fi ìdí ìwé kejì nípa Púrímù yìí múlẹ̀.