Exodus 1:13 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nítorí náà, wọ́n bẹ̀rẹ̀ sí fi iṣẹ́ àṣekára ni àwọn ọmọ Israẹli lára,
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn ara Egipti si mu awọn ọmọ Israeli sìn li asìnpa:
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Wọ́n sì mú wọn ṣiṣẹ́ àṣekú láìkáánú wọn.