Exodus 1:6 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nígbà tí ó yá, Josẹfu kú, gbogbo àwọn arakunrin rẹ̀ náà kú ní ọ̀kọ̀ọ̀kan títí tí gbogbo ìran náà fi kú tán.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Josefu si kú, ati gbogbo awọn arakunrin rẹ̀, ati gbogbo iran na.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Wáyìí o, Jóṣẹ́fù àti gbogbo àwọn arákùnrin rẹ̀ àti gbogbo ìran náà kú,