Exodus 10:11 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
N ò gbà! Ẹ̀yin ọkunrin nìkan ni kí ẹ lọ sin OLUWA; nítorí pé bẹ́ẹ̀ gan-an ni ẹ fẹ́ àbí?” Wọ́n bá lé wọn jáde kúrò níwájú Farao.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Bẹ̃kọ: ẹnyin ọkunrin ẹ lọ, ki ẹ si sìn OLUWA; eyinì li ẹnyin sá nfẹ́. Nwọn si lé wọn jade kuro niwaju Farao.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Rárá! Ọkùnrin yín nìkan ni kí ó lọ, láti lọ sin OLÚWA, ní wọ̀n ìgbà tí ó jẹ́ pé èyí ni ẹ̀yín ń béèrè fún.” Wọ́n sì lé Mósè àti Árónì kúrò ní iwájú Fáráò.