Exodus 10:27 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ṣugbọn OLUWA Ọlọrun mú kí ọkàn Farao le, kò sì jẹ́ kí wọ́n lọ.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ṣugbọn OLUWA mu àiya Farao le, kò si fẹ́ jẹ ki nwọn lọ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ṣùgbọ́n OLÚWA ṣé ọkàn Fáráò le, kò sì ṣetan láti jẹ́ kí wọn lọ.