Exodus 11:9 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Lẹ́yìn náà OLUWA sọ fún Mose pé, “Farao kò ní gba ọ̀rọ̀ rẹ, kí iṣẹ́ ìyanu mi baà lè di pupọ ní ilẹ̀ Ijipti.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
OLUWA si wi fun Mose pe, Farao ki yio gbọ́ tirẹ; ki a le sọ iṣẹ-iyanu mi di pupọ̀ ni ilẹ Egipti.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
OLÚWA ti sọ fún Mósè pé, “Fáráò yóò kọ̀ láti fetí sílẹ̀ sí ọ kí iṣẹ́ ìyanu mí le pọ̀ sí ní Éjíbítì.”