Exodus 12:26 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nígbà tí àwọn ọmọ yín bá sì bi yín léèrè pé, ‘Kí ni ìtumọ̀ ìsìn yìí?’
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Yio si ṣe nigbati awọn ọmọ nyin ba bi nyin pe, Eredi ìsin yi?
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ní ìgbà tí àwọn ọmọ yín bá béèrè lọ́wọ́ yín, ‘Kí ni ohun tí àjọ yìí túmọ̀ sí fún un yín?’