Exodus 12:41 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ọjọ́ tí ó pé irinwo ọdún ó lé ọgbọ̀n (430) gééré, tí wọ́n ti dé ilẹ̀ Ijipti; ni àwọn eniyan OLUWA jáde kúrò níbẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
O si ṣe li opin irinwo ọdún o le ọgbọ̀n, ani li ọjọ́ na gan, li o si ṣe ti gbogbo ogun OLUWA jade kuro ni ilẹ Egipti.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ní ọjọ́ ti irínwó ọdún ó le ọgbọ̀n (430) pé gan an ni gbogbo ènìyàn jáde kúrò ní ilẹ̀ Éjíbítì.