Exodus 12:49 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ati ẹ̀yin, ati àlejò tí ń gbé ààrin yín, òfin kan ṣoṣo ni ó de gbogbo yín.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ofin kan ni fun ibilẹ ati fun alejò ti o ṣe atipo ninu nyin.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Òfin yìí kan náà ni ó mú àwọn ọmọ tí a bí ni ilẹ̀ náà àti àwọn àlejò tí ń gbé ní àárin yín.”