Exodus 12:50 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Gbogbo àwọn eniyan Israẹli bá ṣe bí àṣẹ tí OLUWA pa fún Mose ati Aaroni.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Bẹ̃ni gbogbo awọn ọmọ Israeli ṣe; bi OLUWA ti fi aṣẹ fun Mose ati Aaroni, bẹ̃ni nwọn ṣe.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Gbogbo àwọn ọmọ Ísírẹ́lì ṣe gẹ́gẹ́ bí OLÚWA ti pàṣẹ fún Mósè àti Árónì.