Exodus 13:18 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ṣugbọn Ọlọrun mú kí wọ́n gba ọ̀nà aṣálẹ̀, ní agbègbè Òkun Pupa, àwọn eniyan Israẹli sì jáde láti ilẹ̀ Ijipti pẹlu ìmúrasílẹ̀ ogun.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ṣugbọn Ọlọrun mu wọn yi lọ li ọ̀na ijù Okun Pupa: awọn ọmọ Israeli jade lọ kuro ni ilẹ Egipti ni ihamọra.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí náà Ọlọ́run darí àwọn ènìyàn rọkọ gba ọ̀nà ihà ní apá okùn pupa. Àwọn ọmọ Ísírẹ́lì jáde kúrò ní ilẹ̀ Éjíbítì pẹ̀lú ìmúra fún ogun.