Exodus 15:10 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ṣugbọn o fẹ́ afẹ́fẹ́ lù wọ́n, òkun sì bò wọ́n mọ́lẹ̀, wọ́n rì bí òjé ninu ibú ńlá.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Iwọ si mu afẹfẹ rẹ fẹ́, okun bò wọn mọlẹ: nwọn rì bi ojé ninu omi nla.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ìwọ fẹ́ èèmí rẹ òkun ru bò wọ́n mọ́lẹ̀ wọ́n rì bí òjé ni àárin omi ńlá.