Exodus 15:13 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
O ti fi ìfẹ́ rẹ tí kì í yẹ̀ ṣe amọ̀nà àwọn eniyan rẹ tí o rà pada, o ti fi agbára rẹ tọ́ wọn lọ sí ibùgbé mímọ́ rẹ.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ninu ãnu rẹ ni iwọ fi ṣe amọ̀na awọn enia na ti iwọ ti rapada: iwọ si nfi agbara rẹ tọ́ wọn lọ si ibujoko mimọ́ rẹ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“Nínú ìfẹ́ rẹ ti kì í ṣákìí ìwọ se amọ̀nà Àwọn ènìyàn náà tí ìwọ ti ràpadà Nínú agbára rẹ ìwọ yóò tọ́ wọn lọ sí ibi ìjókòó rẹ mímọ́.