Exodus 15:21 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Miriamu bá dá orin fún wọn pé, “Ẹ kọrin sí OLUWA, nítorí tí ó ti ja àjàṣẹ́gun tí ó lógo, ó ti da ati ẹṣin ati àwọn ẹlẹ́ṣin sinu Òkun Pupa.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Miriamu si da wọn li ohùn pe, Ẹ kọrin si OLUWA nitoriti o pọ̀ li ogo; ẹṣin ati ẹlẹṣin on li o bì ṣubu sinu okun.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Míríámà kọrin sí wọn báyìí pé: “Ẹ kọrin sí OLÚWA Nítorí òun ni ológo jùlọ Ẹṣin àti ẹni tí ó gùn ún Ni òun bi subú sínú òkun.”