Exodus 15:4 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ó da kẹ̀kẹ́ ogun Farao ati àwọn ọmọ ogun rẹ̀ sinu òkun, ó sì ri àwọn akọni ọmọ ogun rẹ̀ sinu Òkun Pupa.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Kẹkẹ́ Farao ati ogun rẹ̀ li o mu wọ̀ inu okun: awọn ãyo olori ogun rẹ̀ li o si rì ninu Okun Pupa.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Kẹ̀kẹ́-ogun Fáráò àti ogun rẹ̀ ni ó mú wọ inú òkun. Àwọn ọmọ ogun Fáráò tó jáfáfá jùlọ ni ó rì sínú òkun pupa.