Exodus 16:2 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Gbogbo ìjọ eniyan Israẹli bá bẹ̀rẹ̀ sí kùn sí Mose ati Aaroni ninu aṣálẹ̀,
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Gbogbo ijọ awọn ọmọ Israeli si nkùn si Mose ati si Aaroni ni ijù na:
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ní ijù náà ni ìjọ àwọn ènìyàn ti kùn sí Mósè àti Árónì.