Exodus 17:7 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ó sì pe orúkọ ibẹ̀ ní Masa ati Meriba, nítorí ìwà ìka-ẹ̀sùn-síni-lẹ́sẹ̀ tí àwọn ọmọ Israẹli hù, ati nítorí dídán tí wọn dán OLUWA wò, wọ́n ní, “Ṣé OLUWA tún wà láàrin wa ni tabi kò sí mọ́?”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
O si sọ orukọ ibẹ̀ ni Massa, ati Meriba, nitori asọ̀ awọn ọmọ Israeli, ati nitoriti nwọn dan OLUWA wò pe, OLUWA ha mbẹ lãrin wa, tabi kò si?
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ó sì sọ orúkọ ibẹ̀ ni Másá (ìdánwò) àti Méríba (kíkùn) nítorí àwọn ọmọ Ísírẹ́lì sọ̀, wọ́n sì dán OLÚWA wò, wọ́n wí pé, “Ǹjẹ́ OLÚWA ń bẹ láàrin wa tàbí kò sí?”