Exodus 17:8 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Lẹ́yìn èyí ni àwọn ará Amaleki wá, wọ́n sì bá àwọn ọmọ Israẹli jagun ní Refidimu.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nigbana li Amaleki wá, o si bá Israeli jà ni Refidimu.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn ara Ámélékì jáde, wọ́n sì dìde ogun sí àwọn ọmọ Ísírẹ́lì ni Réfídímù.