Exodus 19:22 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ati pé, kí àwọn alufaa tí yóo súnmọ́ ibi tí OLUWA wà, ya ara wọn sí mímọ́, kí n má baà jẹ wọ́n níyà.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Si jẹ ki awọn alufa pẹlu, ti o sunmọ OLUWA, ki o yà ara wọn si mimọ́, ki OLUWA ki o má ba kọlù wọn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Kódà àwọn àlùfáà tí ó ń wá ṣíwájú OLÚWA gbọdọ̀ ya ara wọn sí mímọ́ bí bẹ́ẹ̀ kọ́. OLÚWA yóò kọ lù wọ́n.”