Exodus 19:7 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Mose bá pada wá, ó pe àwọn àgbààgbà Israẹli jọ, ó sì sọ gbogbo ohun tí OLUWA pa láṣẹ fún un fún wọn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Mose si wá o si ranṣẹ pè awọn àgba awọn enia, o si fi gbogbo ọ̀rọ wọnyi lelẹ niwaju wọn ti OLUWA palaṣẹ fun u.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Mósè sì tọ àwọn ènìyàn wá, ó sí pe àwọn àgbààgbà láàárin àwọn ènìyàn jọ. Ó sì gbé gbogbo ọ̀rọ̀ ti OLÚWA pàṣẹ fún un láti sọ ni iwájú wọn.