Exodus 2:25 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ọlọrun bojú wo àwọn eniyan Israẹli, ó sì rí irú ipò tí wọ́n wà.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ọlọrun si bojuwò awọn ọmọ Israeli, Ọlọrun si mọ̀ ọ fun wọn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí náà, Ọlọ́run bojú wo àwọn ará Ísírẹ́lì, Ó sì wà láti gbà wọ́n sílẹ̀.