Exodus 20:22 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
OLUWA ní kí Mose sọ fún àwọn eniyan Israẹli pé, “Ẹ ti rí i fúnra yín pé mo ba yín sọ̀rọ̀ láti ọ̀run wá.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
OLUWA si wi fun Mose pe, Bayi ni ki iwọ ki o wi fun awọn ọmọ Israeli pe, Ẹnyin ri bi emi ti bá nyin sọ̀rọ lati ọrun wá.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
OLÚWA sì sọ fún Mósè pé, “Sọ àwọn nǹkan wọ̀nyí fún àwọn ará Ísírẹ́lì: ‘Ẹ̀yin ti rí i fúnraayín bí èmi ti bá a yín sọ̀rọ̀ láti ọ̀run wá.