Exodus 21:1 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
“Àwọn òfin tí o gbọdọ̀ fún àwọn ọmọ Israẹli nìwọ̀nyí:
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
NJẸ wọnyi ni idajọ ti iwọ o gbekalẹ niwaju wọn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“Wọ̀nyí ni àwọn òfin tí ìwọ yóò gbé sí iwájú wọn: