Exodus 21:5 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ṣugbọn bí ẹrú náà bá fúnra rẹ̀ wí ní gbangba pé òun fẹ́ràn olówó òun, ati aya òun, ati àwọn ọmọ òun, nítorí náà òun kò ní gba ìdásílẹ̀, kí òun má baà fi wọ́n sílẹ̀,
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Bi ẹru na ba si wi ni gbangba pe, Emi fẹ́ oluwa mi, aya mi, ati awọn ọmọ mi; emi ki yio jade lọ idi omnira:
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“Bí ìwọ̀fà náà bá sọ gbangba pé, mo fẹ́ràn olówó mi, ìyàwó mi àti àwọn mi èmi kò sì fẹ́ ẹ́ gba òmíràn mọ́: