Exodus 24:17 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Lójú àwọn eniyan Israẹli, ìrísí ògo OLUWA lórí òkè náà dàbí iná ńlá tí ń jóni ní àjórun.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Iwò ogo OLUWA dabi iná ajonirun li ori òke na li oju awọn ọmọ Israeli.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ni ojú àwọn ọmọ Ísírẹ́lì ògo OLÚWA náà dà bí iná ajónirun ni orí òkè.