Exodus 25:18 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Fi wúrà tí wọ́n fi ọmọ owú lù ṣe Kerubu meji, kí ọ̀kọ̀ọ̀kan wà ní ẹ̀gbẹ́ kinni keji ìtẹ́ àánú náà.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Iwọ o si ṣe kerubu wurà meji; ni iṣẹ lilù ni ki iwọ ki o fi ṣe wọn, ni ìku itẹ́-ãnu na mejeji.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Fi wúrà tí a lù se kérúbù méjì sí igun ìtẹ́-àánú.