Exodus 25:8 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
kí wọ́n sì ṣe ibùgbé fún mi, kí n lè máa gbé ààrin wọn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ki nwọn ki o si ṣe ibi mimọ́ kan fun mi; ki emi ki o le ma gbé ãrin wọn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“Nígbà náà ni ìwọ yóò jẹ́ kí wọn kọ́ ibi mímọ́ fún mi. Èmi yóò sì máa gbé ní àárin wọn.