Exodus 32:22 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Aaroni bá dáhùn, ó ní, “Má bínú, oluwa mi, ṣebí ìwọ náà mọ àwọn eniyan wọnyi pé eeyankeeyan ni wọ́n,
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Aaroni si wipe, Máṣe jẹ ki ibinu oluwa mi ki o gbona: iwọ mọ̀ awọn enia yi pe, nwọn buru.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Árónì dáhùn wí pé, “Má ṣe bínú OLÚWA mi. Ìwọ mọ bí àwọn ènìyàn yìí ṣe burú tó.