Exodus 32:35 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nítorí náà, nígbà tó yá, Ọlọrun rán àjàkálẹ̀ àrùn burúkú kan sáàrin àwọn eniyan náà, nítorí pé wọ́n mú kí Aaroni fi wúrà yá ère mààlúù fún wọn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
OLUWA si yọ awọn enia na lẹnu, nitoriti nwọn ṣe ẹgbọrọ-malu, ti Aaroni ṣe.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
OLÚWA sì yọ àwọn ènìyàn náà lẹ́nu, pẹ̀lú arun nítorí ohun tí wọ́n se ni ti ẹgbọrọ màlúù tí Árónì ṣe.