Exodus 33:15 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Mose wí fún OLUWA pé, “Bí o kò bá ní bá wa lọ, má wulẹ̀ kó wa kúrò níhìn-ín.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
On si wi fun u pe, Bi oju rẹ kò ba bá wa lọ, máṣe mú wa gòke lati ihin lọ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà náà ni, Mósè wí fún-un pé, “Bí ojú rẹ kò bá bá wa lọ, má se rán wa gòkè láti ìhín lọ.