Exodus 34:35 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Àwọn ọmọ Israẹli ṣe akiyesi ojú Mose, pé ó ń kọ mànàmànà; Mose a sì máa fi aṣọ ìbòjú bo ojú rẹ̀ títí yóo fi di ìgbà tí yóo tún wọ ilé lọ láti bá OLUWA sọ̀rọ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn ọmọ Israeli si ri oju Mose pe, awọ, oju rẹ̀ ndán: Mose si tun fi iboju bò oju rẹ̀, titi o fi wọle lọ bá a sọ̀rọ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
wọ́n sì rí i pé ojú rẹ̀ ń dán. Mósè á sì tún fi ìbòjú bo ojú rẹ̀ títí á fi lọ bá OLÚWA sọ̀rọ̀.