Exodus 35:1 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Mose pe gbogbo àwọn ọmọ Israẹli jọ, ó wí fún wọn pé, “Àwọn nǹkan tí OLUWA pa láṣẹ pé kí ẹ máa ṣe nìwọ̀nyí:
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
MOSE si pè apejọ gbogbo ijọ awọn ọmọ Israeli, o si wi fun wọn pe, Wọnyi li ọ̀rọ ti OLUWA palaṣẹ pe, ki ẹnyin ki o ṣe wọn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Mósè pe gbogbo ìjọ Ísírẹ́lì ó sì wí fún wọn pé, “Wọ̀nyí ni àwọn ohun ti OLÚWA ti pa láṣẹ fún-un yín láti ṣe: