Exodus 35:18 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Àwọn èèkàn àgọ́, ati àwọn èèkàn àgbàlá pẹlu àwọn okùn wọn;
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ekàn agọ́ na, ati ekàn agbalá na, ati okùn wọn;
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Èèkàn àgọ́ náà fún Àgọ́ náà àti fún àgbàlá àti okùn wọn;