Exodus 35:33 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
láti gé oríṣìíríṣìí òkúta iyebíye ati láti tò wọ́n, bẹ́ẹ̀ náà ni igi gbígbẹ́ ati oríṣìíríṣìí iṣẹ́ ọnà ṣíṣe.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ati li okuta gbigbẹ́ lati tò wọn, ati ni igi fifin, lati ṣiṣẹ li onirũru iṣẹ-ọnà.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
láti gbẹ́ òkúta àti láti tò ó, láti fún igi àti láti sísẹ ni gbogbo onírúurú iṣẹ́ ọnà.