Exodus 35:34 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ọlọrun sì ti mí ìmísí rẹ̀ sí i ninu láti kọ́ ẹlòmíràn, àtòun ati Oholiabu ọmọ Ahisamaki láti inú ẹ̀yà Dani.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
O si fi sinu ọkàn rẹ̀ lati ma kọni, ati on, ati Oholiabu, ọmọ Ahisamaki, ti ẹ̀ya Dani.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ó sì fún òun àti Óhólíábù ọmọ Áhísámákì ti ẹ̀yà Dánì, ni agbára láti kọ́ àwọn tókù.