Exodus 36:10 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ó rán marun-un ninu àwọn aṣọ títa náà pọ̀, ó sì rán marun-un yòókù pọ̀ lọ́tọ̀ọ̀tọ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
O si so aṣọ-tita marun lù mọ́ ara wọn: ati aṣọ-tita marun keji li o si solù mọ́ ara wọn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Wọ́n sì pa aṣọ títa márùn-ún pọ̀ mọ̀ ara wọn, wọ́n sì tún ṣe bẹ́ẹ̀ sì márùn-ún tó kù.